John 7:1

Jesu lọ sí àjọ ìpàgọ́

1Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí Jesu ń rìn ní Galili: nítorí tí kò fẹ́ rìn ní Judea, nítorí àwọn Júù ń wá a láti pa.
Copyright information for YorBMYO